Yorùbá Bibeli

Joṣ 21:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBANA ni awọn olori awọn baba awọn ọmọ Lefi sunmọ Eleasari alufa, ati Joṣua ọmọ Nuni, ati awọn olori awọn baba ẹ̀ya awọn ọmọ Israeli;

Joṣ 21

Joṣ 21:1-5