Yorùbá Bibeli

Joṣ 19:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ninu ipín awọn ọmọ Juda ni awọn ọmọ Simeoni ni ilẹ-iní: nitori ipín awọn ọmọ Juda pọ̀ju fun wọn: nitorina ni awọn ọmọ Simeoni fi ní ilẹ-iní lãrin ilẹ-iní wọn.

Joṣ 19

Joṣ 19:1-10