Yorùbá Bibeli

Joṣ 19:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣẹri lọ si ìha ìla-õrùn dé Beti-dagoni, o si dé Sebuluni, ati afonifoji Ifta-eli ni ìha ariwa dé Betemeki, ati Neieli; o si yọ si Kabulu li apa òsi,

Joṣ 19

Joṣ 19:21-37