Yorùbá Bibeli

Joṣ 18:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin na si lọ, nwọn si là ilẹ na já, nwọn si ṣe apejuwe rẹ̀ sinu iwé ni ilu ilu li ọ̀na meje, nwọn si pada tọ̀ Joṣua wá, si ibudó ni Ṣilo.

Joṣ 18

Joṣ 18:6-15