Yorùbá Bibeli

Joṣ 18:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Àla wọn ni ìha ariwa si ti Jordani lọ; àla na si gòke lọ si ìha Jeriko ni ìha ariwa, o si là ilẹ òke lọ ni iwọ-õrùn; o si yọ si aginjù Beti-afeni.

Joṣ 18

Joṣ 18:8-14