Yorùbá Bibeli

Joṣ 17:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti awọn ọmọbinrin Manasse ní ilẹ-iní lãrin awọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin: awọn ọmọ Manasse ọkunrin iyokù si ní ilẹ Gileadi.

Joṣ 17

Joṣ 17:1-15