Yorùbá Bibeli

Joṣ 17:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si da wọn lohùn pe, Bi iwọ ba jẹ́ enia nla, gòke lọ si igbó, ki o si ṣanlẹ fun ara rẹ nibẹ̀ ni ilẹ awọn Perissi ati ti Refaimu; bi òke Efraimu ba há jù fun ọ.

Joṣ 17

Joṣ 17:10-18