Yorùbá Bibeli

Joṣ 17:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni ìha gusù ti Efraimu ni, ati ni ìha ariwa ti Manasse ni, okun si ni àla rẹ̀; nwọn si dé Aṣeri ni ìha ariwa, ati Issakari ni ìha ìla-õrùn.

Joṣ 17

Joṣ 17:8-18