Yorùbá Bibeli

Joṣ 13:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ni afonifoji, Beti-haramu, ati Beti-nimra, ati Sukkotu, ati Safoni, iyokù ilẹ-ọba Sihoni ọba Heṣboni, Jordani ati àgbegbe rẹ̀, titi dé ìha opín okun Kinnereti ni ìha keji Jordani ni ìha ìla-õrùn.

Joṣ 13

Joṣ 13:17-33