Yorùbá Bibeli

Joṣ 13:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Àla wọn bẹ̀rẹ lati Aroeri lọ, ti mbẹ leti afonifoji Arnoni, ati ilu ti mbẹ lãrin afonifoji nì, ati gbogbo pẹtẹlẹ̀ ti mbẹ ni ìha Medeba;

Joṣ 13

Joṣ 13:9-24