Yorùbá Bibeli

Joṣ 12:12-18 Yorùbá Bibeli (YCE)

12. Ọba Egloni, ọkan; ọba Geseri, ọkan;

13. Ọba Debiri, ọkan; ọba Gederi, ọkan;

14. Ọba Horma, ọkan; ọba Aradi, ọkan;

15. Ọba Libna, ọkan; ọba Adullamu, ọkan;

16. Ọba Makkeda, ọkan; ọba Betieli, ọkan;

17. Ọba Tappua, ọkan; ọba Heferi, ọkan;

18. Ọba Afeki, ọkan; ọba Laṣaroni, ọkan;