Yorùbá Bibeli

Joṣ 11:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni Joṣua gbà gbogbo ilẹ na, ilẹ òke, ati gbogbo ilẹ Gusù, ati gbogbo ilẹ Goṣeni, ati ilẹ titẹju, ati pẹtẹlẹ̀, ati ilẹ òke Israeli, ati ilẹ titẹju rẹ̀;

Joṣ 11

Joṣ 11:9-22