Yorùbá Bibeli

Joṣ 11:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati gbogbo ilu awọn ọba wọnni, ati gbogbo ọba wọn, ni Joṣua kó, o si fi oju idà kọlù wọn, o si pa wọn run patapata, gẹgẹ bi Mose iranṣẹ OLUWA ti palaṣẹ.

Joṣ 11

Joṣ 11:6-19