Yorùbá Bibeli

2. Tim 4:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wasu ọ̀rọ na; ṣe aisimi li akokò ti o wọ̀, ati akokò ti kò wọ̀; baniwi, ṣe itọ́ni, gbà-ni-niyanju pẹlu ipamọra ati ẹ̀kọ́ gbogbo.

2. Tim 4

2. Tim 4:1-12