Yorùbá Bibeli

2. Tim 1:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori idi eyiti emi ṣe njìya wọnyi pẹlu: ṣugbọn oju kò tì mi: nitori emi mọ̀ ẹniti emi gbagbọ́, o si da mi loju pe, on le pa ohun ti mo fi le e lọwọ mọ́ titi di ọjọ nì.

2. Tim 1

2. Tim 1:5-16