Yorùbá Bibeli

2. Sam 8:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si fi awọn ologun si Siria ti Damasku: awọn ara Siria si wa sìn Dafidi, nwọn a si ma mu ẹbùn wá. Oluwa si pa Dafidi mọ nibikibi ti o nlọ.

2. Sam 8

2. Sam 8:4-16