Yorùbá Bibeli

2. Sam 7:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ, jẹ ki o wù ọ lati bukún idile iranṣẹ rẹ, ki o wà titi lai niwaju rẹ: nitori iwọ, Oluwa Ọlọrun, li o ti sọ ọ: si jẹ ki ibukún ki o wà ni idile iranṣẹ rẹ titi lai, nipasẹ ibukún rẹ.

2. Sam 7

2. Sam 7:23-29