Yorùbá Bibeli

2. Sam 6:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si gbe apoti-ẹri Ọlọrun na gun kẹkẹ́ titun kan, nwọn si mu u lati ile Abinadabu wá, eyi ti o wà ni Gibea: Ussa ati Ahio, awọn ọmọ Abinadabu si ndà kẹkẹ́ titun na.

2. Sam 6

2. Sam 6:2-7