Yorùbá Bibeli

2. Sam 6:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wi fun Mikali pe, Niwaju Oluwa ni, ẹniti o yàn mi fẹ jù baba rẹ lọ, ati ju gbogbo idile rẹ̀ lọ, lati fi emi ṣe olori awọn enia Oluwa, ani lori Israeli, emi o si ṣire niwaju Oluwa.

2. Sam 6

2. Sam 6:11-23