Yorùbá Bibeli

2. Sam 6:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi apoti-ẹri Oluwa si ti wọ̀ ilu Dafidi wá; Mikali ọmọbinrin Saulu si wò lati oju ferese, o si ri Dafidi ọba nfò soke o si njo niwaju Oluwa; on si kẹgàn rẹ̀ li ọkàn rẹ̀.

2. Sam 6

2. Sam 6:6-19