Yorùbá Bibeli

2. Sam 5:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yìo si ṣe, nigbati iwọ ba gbọ́ iro ẹsẹ lori awọn igi Baka na, nigbana ni iwọ o si yara, nitoripe nigbana li Oluwa yio jade lọ niwaju rẹ, lati kọlu ogun awọn Filistini.

2. Sam 5

2. Sam 5:21-25