Yorùbá Bibeli

2. Sam 5:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si bere lọdọ Oluwa, pe, Ki emi ki o goke tọ̀ awọn Filistini bi? iwọ o fi wọn le mi lọwọ bi? Oluwa si wi fun Dafidi pe, Goke lọ: nitoripe, dajudaju emi o fi awọn Filistini le ọ lọwọ.

2. Sam 5

2. Sam 5:9-21