Yorùbá Bibeli

2. Sam 4:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn wọ ile na lọ, on si dubulẹ lori ibusun rẹ̀ ninu iyẹwu rẹ̀, nwọn si lu u pa, nwọn si bẹ ẹ li ori, nwọn gbe ori rẹ̀, nwọn si fi gbogbo oru rìn ni pẹtẹlẹ na.

2. Sam 4

2. Sam 4:2-12