Yorùbá Bibeli

2. Sam 4:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si fi aṣẹ fun awọn ọdọmọkunrin rẹ̀, nwọn si pa wọn, nwọn si ke ọwọ́ ati ẹṣẹ wọn, a si fi wọn ha lori igi ni Hebroni. Ṣugbọn nwọn mu ori Iṣboṣeti, nwọn si sin i ni iboji Abneri ni Hebroni.

2. Sam 4

2. Sam 4:2-12