Yorùbá Bibeli

2. Sam 3:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Joabu si jade kuro lọdọ Dafidi, o si ran awọn iranṣẹ lepa Abneri, nwọn si pè e pada lati ibi kanga Sira: Dafidi kò si mọ̀.

2. Sam 3

2. Sam 3:18-29