Yorùbá Bibeli

2. Sam 3:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ, ẹ ṣe e: nitoriti Oluwa ti sọ fun Dafidi pe, Lati ọwọ́ Dafidi iranṣẹ mi li emi o gbà Israeli enia mi là kuro lọwọ awọn Filistini ati lọwọ gbogbo awọn ọta wọn.

2. Sam 3

2. Sam 3:15-27