Yorùbá Bibeli

2. Sam 3:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

OGUN na si pẹ titi larin idile Saulu ati idile Dafidi: agbara Dafidi si npọ̀ si i, ṣugbọn idile Saulu nrẹ̀hin si i.

2. Sam 3

2. Sam 3:1-4