Yorùbá Bibeli

2. Sam 2:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin Juda si wá, nwọn si fi Dafidi jọba nibẹ lori ile Juda. Nwọn si sọ fun Dafidi pe, Awọn ọkunrin Jabeṣi Gileadi li o sinkú Saulu.

2. Sam 2

2. Sam 2:1-14