Yorùbá Bibeli

2. Sam 2:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joabu si dẹkun ati ma tọ Abneri lẹhin: o si ko gbogbo awọn enia na jọ, enia mọkandi-logun li o kú pẹlu Asaheli ninu awọn iranṣẹ Dafidi.

2. Sam 2

2. Sam 2:27-32