Yorùbá Bibeli

2. Sam 2:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Abneri si tun wi fun Asaheli pe, Pada lẹhin mi, ẽṣe ti emi o fi lu ọ bolẹ? bawo li emi o ti ṣe gbe oju soke si Joabu arakunrin rẹ?

2. Sam 2

2. Sam 2:13-24