Yorùbá Bibeli

2. Sam 2:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joabu ọmọ Seruia, ati awọn iranṣẹ Dafidi si jade, nwọn si jọ pade nibi adagun Gibeoni: nwọn si joko, ẹgbẹ kan li apa ihin adagun, ẹgbẹ keji li apa keji adagun.

2. Sam 2

2. Sam 2:9-15