Yorùbá Bibeli

2. Sam 2:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe lẹhin eyi, Dafidi si bere lọwọ Oluwa, pe, Ki emi ki o goke lọ si ọkan ni ilu Juda wọnni bi? Oluwa si wi fun u pe, Goke lọ: Dafidi si wipe, niha ibo ni ki emi ki o lọ? On si wipe, Ni Hebroni.

2. Sam 2

2. Sam 2:1-8