Yorùbá Bibeli

2. Kor 13:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe a kàn a mọ agbelebu nipa ailera, ṣugbọn on wà lãye nipa agbara Ọlọrun. Nitori awa pẹlu jasi alailera ninu rẹ̀, ṣugbọn awa ó wà lãye pẹlu rẹ̀ nipa agbara Ọlọrun si nyin.

2. Kor 13

2. Kor 13:3-8