Yorùbá Bibeli

2. Kor 13:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li akotan, ará, odigboṣe. Ẹ jẹ pipé, ẹ tújuka, ẹ jẹ oninu kan, ẹ mã wà li alafia; Ọlọrun ifẹ ati ti alafia yio wà pẹlu nyin.

2. Kor 13

2. Kor 13:6-14