Yorùbá Bibeli

2. Kor 10:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ṢUGBỌN emi Paulu tikarami fi inu tutù ati ìwa pẹlẹ Kristi bẹ̀ nyin, emi ẹni irẹlẹ loju nyin nigbati mo wà larin nyin, ṣugbọn nigbati emi kò si, mo di ẹni igboiya si nyin.

2. Kor 10

2. Kor 10:1-2