Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 8:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ọba si bère lọwọ obinrin na, o rohin fun u. Ọba si yàn iwẹ̀fa kan fun u, wipe, Mu ohun gbogbo ti iṣe ti rẹ̀ pada fun u, ati gbogbo erè oko lati ọjọ ti o ti fi ilẹ silẹ titi di isisiyi.

2. A. Ọba 8

2. A. Ọba 8:5-9