Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 8:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joramu ọba si pada si Jesreeli lati wò ọgbẹ́ ti awọn ara Siria ti ṣa a ni Rama, nigbati o mba Hasaeli ọba Siria ja. Ahasiah ọmọ Jehoramu ọba Juda sọ̀kalẹ lati wá iwò Joramu ọmọ Ahabu ni Jesreeli nitoriti o nṣe aisàn.

2. A. Ọba 8

2. A. Ọba 8:24-29