Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 8:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati li ọdun karun Joramu, ọmọ Ahabu ọba Israeli, Jehoṣafati jẹ ọba Juda: nigbana Jehoramu ọmọ Jehoṣafati ọba Juda bẹ̀rẹ si ijọba.

2. A. Ọba 8

2. A. Ọba 8:9-25