Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 8:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ELIṢA si wi fun obinrin na, ọmọ ẹniti o ti sọ di ãyè, wipe, Dide, si lọ, iwọ ati ile rẹ, ki o si ṣe atipo nibikibi ti iwọ ba le ṣe atipo: nitoriti Oluwa pe ìyan: yio si mu pẹlu ni ilẹ, li ọdun meje.

2. A. Ọba 8

2. A. Ọba 8:1-4