Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 7:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni nwọn wi fun ara wọn pe, Awa kò ṣe rere: oni yi, ọjọ ihinrere ni, awa si dakẹ: bi awa ba duro titi di afẹmọjumọ, iyà yio jẹ wa: njẹ nisisiyi ẹ wá, ẹ jẹ ki a si lọ isọ fun awọn ara ile ọba.

2. A. Ọba 7

2. A. Ọba 7:6-16