Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 7:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ijòye na si da enia Ọlọrun na li ohùn, o si wipe, Kiyesi i, nisisiyi, bi Oluwa tilẹ ṣe ferese li ọrun, iru nkan yi ha le ri bẹ̃? On si wipe, Kiyesi i, iwọ o fi oju rẹ ri i, ṣugbọn iwọ kì yio jẹ ninu rẹ̀.

2. A. Ọba 7

2. A. Ọba 7:18-20