Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 7:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBANA ni Eliṣa wipe, Ẹ gbọ́ ọ̀rọ Oluwa: Bayi li Oluwa wi, Ni iwòyi ọla li a o ta oṣùwọn iyẹ̀fun kikuna kan ni ṣekeli kan ni ẹnu bode Samaria.

2. A. Ọba 7

2. A. Ọba 7:1-4