Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 6:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi on ti mba wọn sọ̀rọ lọwọ, kiyesi i, iranṣẹ na sọ̀kalẹ tọ̀ ọ wá: on si wipe, Wò o, lati ọwọ Oluwa ni ibi yi ti wá, kili emi o ha duro dè Oluwa mọ si?

2. A. Ọba 6

2. A. Ọba 6:32-33