Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 6:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si wi fun u pe, Ẽṣe ọ? On si dahùn wipe, Obinrin yi wi fun mi pe, Mu ọmọkunrin rẹ wá, ki awa ki o le jẹ ẹ loni, awa o si jẹ ọmọ ti emi li ọla.

2. A. Ọba 6

2. A. Ọba 6:23-33