Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 6:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iyàn nla kan si mu ni Samaria: si kiyesi i, nwọn dó tì i, tobẹ̃ ti a si fi ntà ori kẹtẹkẹtẹ kan ni ọgọrun iwọ̀n fadakà, ati idamẹrin oṣuwọn kabu imi ẹiyẹle, ni iwọ̀n fàdakà marun.

2. A. Ọba 6

2. A. Ọba 6:16-33