Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 6:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eliṣa si gbadura, o si wipe, Oluwa, emi bẹ̀ ọ, là a li oju, ki o lè riran. Oluwa si là oju ọdọmọkunrin na; on si riran: si wò o, òke na kún fun ẹṣin ati kẹkẹ́-iná yi Eliṣa ka.

2. A. Ọba 6

2. A. Ọba 6:9-22