Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 5:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati Eliṣa enia Ọlọrun gbọ́ pe, ọba Israeli fà aṣọ rẹ̀ ya, o si ranṣẹ si ọba wipe, Ẽṣe ti iwọ fi fà aṣọ rẹ ya? jẹ ki o tọ̀ mi wá nisisiyi, on o si mọ̀ pe, woli kan mbẹ ni Israeli.

2. A. Ọba 5

2. A. Ọba 5:5-15