Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 5:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si mu iwe na tọ̀ ọba Israeli wá, wipe, Njẹ nisisiyi nigbati iwe yi ba de ọdọ rẹ, kiyesi i, emi rán Naamani iranṣẹ mi si ọ, ki iwọ ki o le wò o sàn kuro ninu ẹ̀tẹ rẹ̀.

2. A. Ọba 5

2. A. Ọba 5:1-16