Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 5:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ẹ̀tẹ Naamani yio lẹ mọ ọ, ati iru-ọmọ rẹ titi lai. On si jade kuro niwaju rẹ̀, li adẹtẹ̀ ti o funfun bi ojodidì.

2. A. Ọba 5

2. A. Ọba 5:25-27