Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 5:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn on wipe, Bi Oluwa ti mbẹ, niwaju ẹniti emi duro, emi kì yio gbà nkan. O si rọ̀ ọ ki o gbà, ṣugbọn on kọ̀.

2. A. Ọba 5

2. A. Ọba 5:9-22